X hits on this document

65 views

0 shares

0 downloads

0 comments

1 / 5

Anti Ahmadiyya Movement in Islam

27th February 200

IRETI AWON QADIANI DI OFO

Dr Syed Rashid Ali

Assalam Alaikum,

Opolopo awon Musulumi ni komo nipa ijo awon Qadiani rara, awon ni omolehin enikan to npe ara re ni anabi ohun ni ogbeni Mirza Ghulam ti o lo gbimo po pelu awon kan ti anpe ni British Raj lati fi abuku kan esin Islam nilu India ni asoko odun 19th ati 20th century.  Awon ni monafiki ti won npe ara won ni Musulumi.  Olori won ti so wipe awa ti a ntele Anobi wa Muhammed (SAW) je keferi.  Bakanna ni awon ojogbon Musulumi agbaiye ti panupo pelu orile ede Pakistani wipe awon ijo Qadiani gan ni ki se Musulumi rara.

Nilu Pakistani na awon ijo Qadiani yi lero wipe won tun ma gba won pada si ajo Musulumi lasiko ti Olori ilu na, ti a npe ni Musharraf ti fagi le iwe ofin ilu.  Nitori wi pe ijoba Musharraf ko fa ye gba esin Islam bi tatehin wa. Eyi lo muki ijo Qadiani ma lero pe awon ti di Musulumi pada.

Ope ni fun Oluwa, ero awon Qadiani ko wole.

Ijoba so wipe ijo Qadiani kise ijo Musulumi.

Agbenuso fun ijoba ni ojo 24th Feb so pe gbogbo awon toje omo egbe Qadiani ti won pera won ni ijo Ahmadi won ki se Musulumi. Ijoba ko ka won kun Musulumi.  Ijoba tun so bakanna pe nkan ti iwe ofin so ni (Ijoba fara mo).  Ijoba so wipe ko si iyato ninu ofin ti awon se pelu ofim to wale ni le. Ko si aye fun ijo Qadiani rara ni ilu Pakistan.  Won si so pe iro ni oro ta won agbenuso kan so pe Ijoba tuntun kobikita mo nipa Qadiani mo. Gbogbo ikan ti ofin so ni Ijoba faramo. Awon ikan meji ni esin Islam gbagbo. Awon ni Aluquran ati Sunnah Anabi Mohammed (SAW).  Gbogbo eniti o ba gba fun Islam ni lati tele ona mejeji na. Eyi to se pataki ju ni wipe a ko gbodo sin nkan miran ayafi Olohun Allah. Eleyi ni idaji akoko ti mususlumi lati gba. Idaji ekeji ni wipe Anobi Mohammed je Ojise Olohun. Awon nkan miran ti Musulumi lati se ati pe ti oni lati gbagbo wa sugbon, awon ti a wi siwaju yi ni o je pataki ju awon oro miran.

Awon elomiran nipa aimokan a ma so eyiti o wun won. A ma so opolopo oro ni ori eleyi ni ojo iwaju, sugbon a so die lori iru awon ijo ti won fi aimokan ko ara won jo gegebi apere –

Document info
Document views65
Page views65
Page last viewedMon Jan 16 15:29:15 UTC 2017
Pages5
Paragraphs45
Words2335

Comments