X hits on this document

68 views

0 shares

0 downloads

0 comments

2 / 5

-  Nation of Islam

-  The Nation of Gods and Earths (5 Nation of Islam)

-  Ijo International Community of Submittes

Awon Ijo Nation of Islam

Awon eleyi pera won ni (Nation of Islam).  Won ni igbagbo wipe Olohun kan lowa.  Olohun kanna si fi ara han ni abara ogbeni W. Fard Muhammed ni osu July, 1990, ohun ni messiah ti awon omo Christian nreti ohun ni Messiah ti awon omo Christian nreti. Ohun kanna ni Mahdi ti awon ti Musulumi.  Sugbon sa, Alukurani, Sura kerin (4) ayat 36 sowipe “Esin Olohun Allah, ki e ma se ba Olohun wa orogun”.  Bakana ni hadith Bukhari, “Aisha sope ti eni kan ba so fun yin pe Anabi Muhammed (SWA) ri Oluwa Olohun re, opuro ni onitohun.  Nitori pe Olohun Allah so ni Sura kefa (6) ayat 103 wipe kosi oju kan tole ri Olohun”.

Ninu awon nkan ti ijo (Nation of Islam) gbagbo ni igbedide Oku. Ki se igbedide ti ara bi ko se ti emi.  Won ni awon ni igbagbo pe iran enia dudu ni won yio jidide ni ti emi.  Nitori idi eyi awon ni yio koko dide.  Sugbon sa, Alukurani fi da wa loju ni Sura 20 ayat 55 wipe “Lati inu ile ni ati da yin, ninu re ni A o da yin pada si ninu re na ni A o tun gbeyin dide lekan si”.  Lehin na Alukurani tun so ni Sura 64 ayat 7 wipe “Awon Alaigbagbo lero pe won koni gbe won dide fun idajo.  So fun won pe beni ni Ashe Oluwa mi, A o gbe yin dide. Nigbana ni eyin yio gbo ododo gbogbo nkan ti e gbe ile aiye se.  Eleyi si rorun fun Olohun Allah lati se lehin awon nkan meji ti a toka si sehin, awon ijo (Nation of Islam) tun ni igbagbo ninu awon nkan miran yato si ti Islam, eyi ti Alukurani ati Sunna fi ko wa.

Apere eleyi ni nkan ti won so wipe (A wa Musulumi alawo dudu) gbagbo ninu ododo ti o wa ninu Bibeli, bi o ti le je pe won ti da Bibeli ru, awa ni lati se atunse alaye fun awon enia kia won ma ba sina pelu gbogbo modaru towa ninu Bibeli “ Awon abuku to wa ninu igbagbo yi ni pe, Anabi Muhammed ko so pe ki a gba oro Bibeli gbo, ko si lodi si, bakanna Ko si so pe ki a se atunse si oro Bibeli.  Awon ijo yi tun so bayi pe “Awa ti a pe ara wa ni Musulumi ododo, akogbodo ko pa ni ogun jija eyi ti o ma gba emi awon enia.  Awa ko gbagbo pe won ni lati je wa ni pa lati ko pa ninu awon ogun nitoripe ko si anfani kan kan ninu re ayafi ki Ijoba America ba fun wa ni ile (land) ti o je ti wa eyi ti o le mu ki awa na le ja fun.”  Abuku to wa ni nu iru fe igbagbo yi ni pe Alukurani ati Sunnah ti fo oro na si we we, nipa pe ti idi pataki ba wa lati jagun, Musulumi ni lati jagun fun idi pataki.

The Nation of Gods and Earths (5% Nation of Islam)

Ijo yi je eyi ti o ya pa kuro ninu (Nation of Islam) ti a ti soro re wa.   Gege bi ti ikeji awon ikan ti won gbagbo ti yato pupo si oro Islam.  Ti

Document info
Document views68
Page views68
Page last viewedTue Jan 24 09:41:45 UTC 2017
Pages5
Paragraphs45
Words2335

Comments