X hits on this document

66 views

0 shares

0 downloads

0 comments

5 / 5

A tun ri ninu iwa ogbeni khalifa-enikan ti ma lo agbara imo ikoko nkan ti yio sele lola.  O so asotele igbati aiye yio pare. Sugbon Olohun so ninu Alukuriani sura 7 ayat 187 pe:-“Ti won ba bere lowo re nipa imo asiko na, igbawo ni yi o de? So fun won pe imo asiko na wa lodo Olohun mi.  Ko si enikan ayafi Olohun nikan ni O mo asiko na.  Ni ojo na, aiye ati orun yio mi titi lojiji ni asiko na yio de.  Tiwon ba be re igbawo, so pe imo na  wa lodo Olohun!!

Awon ijo ijuraenisile (Submitters) ko gba sunnah Anabi Mohammed (S.A.W) gbogbo rara.  Ki se pe won gba apakan gbo, ti won ko gba apakeji, gbogbo sunnah Anabi ni won ko gba.  Loju won, Sunnah ki se ona ti Islam. Abuku to wa ninu oro yi ni pe, awon ijo yi ba gbogbo opo islam je pata pata.  Nitori pe won ko nile kirun eyi tio je opo keji Islam, bakanna, won ko le yan zaka to je opo keta won ko le gba awe to je opo kerin bakanna irin ajo hajj to je karun, awon ijo yi ko ni le se won ni gbati won tako sunnah Anobi.

Niwon igbati won ti kuna ni merin ninu opo marun, eyi ti fi han wipe awon ijo na ko le pe ra won ni Musulumi.

Anti Movement Ahmadiyya en Islam

Dr. SEYD RASHID ALI

P.O. BOX 11560

DIBBA Al  FUJAIRAH, United Arab Emirates

Fax : 00971 9 2 442846

rayed@emirates. net.ae http://alhafeez.org/rashid/

Document info
Document views66
Page views66
Page last viewedThu Jan 19 17:07:55 UTC 2017
Pages5
Paragraphs45
Words2335

Comments